Sáàmù 42:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mò* ń wá Ọlọ́run, Ọlọ́run alààyè, bí ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ ṣe ń wá omi.+ Ìgbà wo ni kí n wá, kí n sì fara hàn níwájú Ọlọ́run?+ Sáàmù 63:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, mò ń wá ọ.+ Ọkàn mi ń fà sí ọ.*+ Àárẹ̀ ti mú mi* nítorí bó ṣe ń wù mí láti rí ọNí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú, níbi tí kò sí omi.+ Émọ́sì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí,‘Nígbà tí màá rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,Kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí ti omi,Bí kò ṣe ti gbígbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà.+ Mátíù 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Aláyọ̀ ni àwọn tí ebi òdodo ń pa,+ tí òùngbẹ òdodo sì ń gbẹ, torí wọ́n máa yó.*+
2 Mò* ń wá Ọlọ́run, Ọlọ́run alààyè, bí ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ ṣe ń wá omi.+ Ìgbà wo ni kí n wá, kí n sì fara hàn níwájú Ọlọ́run?+
63 Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, mò ń wá ọ.+ Ọkàn mi ń fà sí ọ.*+ Àárẹ̀ ti mú mi* nítorí bó ṣe ń wù mí láti rí ọNí ilẹ̀ tó gbẹ táútáú, níbi tí kò sí omi.+
11 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí,‘Nígbà tí màá rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,Kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí ti omi,Bí kò ṣe ti gbígbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà.+