Sáàmù 97:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 145:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Jèhófà ń ṣọ́ gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+Àmọ́ yóò pa gbogbo ẹni burúkú run.+
10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+