1 Kíróníkà 29:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bákan náà, nítorí ìfẹ́ tí mo ní fún ilé Ọlọ́run mi,+ mo fi wúrà àti fàdákà sílẹ̀ látinú àwọn ohun iyebíye mi+ fún ilé Ọlọ́run mi, láfikún sí gbogbo ohun tí mo ti fi sílẹ̀ fún ilé mímọ́ náà, Sáàmù 26:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà, mo nífẹ̀ẹ́ ilé tí ò ń gbé,+Ibi tí ògo rẹ wà.+ Sáàmù 69:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìtara ilé rẹ ti gbà mí lọ́kàn,+Ẹ̀gàn ẹnu àwọn tó ń pẹ̀gàn rẹ sì ti wá sórí mi.+
3 Bákan náà, nítorí ìfẹ́ tí mo ní fún ilé Ọlọ́run mi,+ mo fi wúrà àti fàdákà sílẹ̀ látinú àwọn ohun iyebíye mi+ fún ilé Ọlọ́run mi, láfikún sí gbogbo ohun tí mo ti fi sílẹ̀ fún ilé mímọ́ náà,