Ẹ́kísódù 23:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Oyún kò ní bà jẹ́ lára àwọn obìnrin ilẹ̀ yín, wọn ò sì ní yàgàn.+ Màá jẹ́ kí ẹ̀mí yín gùn dáadáa.* Sáàmù 127:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wò ó! Àwọn ọmọ* jẹ́ ogún láti ọ̀dọ̀ Jèhófà;+Èso ikùn* jẹ́ èrè.+
26 Oyún kò ní bà jẹ́ lára àwọn obìnrin ilẹ̀ yín, wọn ò sì ní yàgàn.+ Màá jẹ́ kí ẹ̀mí yín gùn dáadáa.*