ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 7:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+

  • 1 Àwọn Ọba 8:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ó jẹ́ ìfẹ́ ọkàn Dáfídì bàbá mi pé kí ó kọ́ ilé fún orúkọ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+

  • 1 Kíróníkà 15:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Lẹ́yìn náà, Dáfídì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ sí Jerúsálẹ́mù láti gbé Àpótí Jèhófà wá sí ibi tí ó ti ṣètò sílẹ̀ fún un.+

  • 1 Kíróníkà 15:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ni olórí agbo ilé àwọn ọmọ Léfì. Ẹ ya ara yín sí mímọ́, ẹ̀yin àti àwọn arákùnrin yín, kí ẹ sì gbé Àpótí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá sí ibi tí mo ti ṣètò sílẹ̀ fún un.

  • Ìṣe 7:45, 46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Àwọn baba ńlá wa jogún rẹ̀, wọ́n sì gbé e wá nígbà tí wọ́n ń tẹ̀ lé Jóṣúà bọ̀ ní ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+ àwọn tí Ọlọ́run lé jáde kúrò níwájú àwọn baba ńlá wa.+ Ó sì wà níbẹ̀ títí di ìgbà ayé Dáfídì. 46 Ó rí ojú rere Ọlọ́run, ó sì ní kó fún òun láǹfààní láti kọ́ ibùgbé fún Ọlọ́run Jékọ́bù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́