ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 3:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Fa iṣẹ́ lé Jóṣúà lọ́wọ́,+ kí o fún un ní ìṣírí, kí o sì mú un lọ́kàn le, torí òun ló máa kó àwọn èèyàn yìí sọdá,+ òun ló sì máa mú kí wọ́n jogún ilẹ̀ tí wàá rí.’

  • Diutarónómì 31:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló máa sọdá ṣáájú rẹ, òun fúnra rẹ̀ máa pa àwọn orílẹ̀-èdè yìí run kúrò níwájú rẹ, wàá sì lé wọn kúrò.+ Jóṣúà ló máa kó yín sọdá,+ bí Jèhófà ṣe sọ gẹ́lẹ́.

  • Jóṣúà 3:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tí àwọn èèyàn náà kúrò nínú àgọ́ wọn, kété kí wọ́n tó sọdá Jọ́dánì, àwọn àlùfáà tó gbé àpótí+ májẹ̀mú ń lọ níwájú àwọn èèyàn náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́