-
Àwọn Onídàájọ́ 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mo gbà yín lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì àti lọ́wọ́ gbogbo àwọn tó ń fìyà jẹ yín, mo lé wọn kúrò níwájú yín, mo sì fún yín ní ilẹ̀ wọn.+
-