Diutarónómì 32:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”* Sáàmù 117:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 117 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;+Ẹ gbé e ga, gbogbo ẹ̀yin èèyàn.*+ Àìsáyà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.
43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”*
10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.