Sáàmù 37:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+ 40 Jèhófà á ràn wọ́n lọ́wọ́, á sì gbà wọ́n sílẹ̀.+ Á gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú, á sì gbà wọ́n là,Nítorí òun ni wọ́n fi ṣe ibi ààbò.+ Sáàmù 50:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Pè mí ní àkókò wàhálà.+ Màá gbà ọ́ sílẹ̀, wàá sì máa yìn mí lógo.”+
39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+ 40 Jèhófà á ràn wọ́n lọ́wọ́, á sì gbà wọ́n sílẹ̀.+ Á gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú, á sì gbà wọ́n là,Nítorí òun ni wọ́n fi ṣe ibi ààbò.+