ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 49:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ọgbọ́n,

      Àṣàrò ọkàn mi+ yóò sì fi òye hàn.

  • Sáàmù 51:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Jèhófà, ṣí ètè mi,

      Kí ẹnu mi lè máa kéde ìyìn rẹ.+

  • Sáàmù 143:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Mo rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́;

      Mo ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ;+

      Ó ń yá mi lára láti máa ronú lórí* iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.

  • Fílípì 4:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Paríparí rẹ̀, ẹ̀yin ará, ohunkóhun tó jẹ́ òótọ́, ohunkóhun tó ṣe pàtàkì, ohunkóhun tó jẹ́ òdodo, ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́,* ohunkóhun tó yẹ ní fífẹ́, ohunkóhun tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ dáadáa, ohunkóhun tó bá dára, ohunkóhun tó bá yẹ fún ìyìn, ẹ máa ronú* lórí àwọn nǹkan yìí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́