Sáàmù 32:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà) Sáàmù 51:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbé ojú rẹ* kúrò lára àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi,+Kí o sì pa gbogbo ìṣìnà mi rẹ́.*+
5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà)