Sáàmù 43:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+ Kí wọ́n máa darí mi;+Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+ Sáàmù 86:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+
3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+ Kí wọ́n máa darí mi;+Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+
11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+