Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Àìsáyà 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà títí láé,+Torí pé Àpáta ayérayé ni Jáà* Jèhófà.+
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+