Sáàmù 62:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bákan náà, ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ jẹ́ tìrẹ, Jèhófà,+Nítorí o máa ń san kálukú lẹ́san iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.+ 2 Tẹsalóníkà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Èyí jẹ́ nítorí pé Ọlọ́run kà á sí òdodo láti san ìpọ́njú pa dà fún àwọn tó ń pọ́n yín lójú.+