Sáàmù 69:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́, kí àdúrà mi wá sọ́dọ̀ rẹ,Jèhófà, ní àkókò ìtẹ́wọ́gbà.+ Nínú ọ̀pọ̀ ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ìwọ Ọlọ́run,Fi àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ dá mi lóhùn.+ Àìsáyà 55:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ wá Jèhófà nígbà tí ẹ lè rí i.+ Ẹ pè é nígbà tó wà nítòsí.+
13 Àmọ́, kí àdúrà mi wá sọ́dọ̀ rẹ,Jèhófà, ní àkókò ìtẹ́wọ́gbà.+ Nínú ọ̀pọ̀ ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ìwọ Ọlọ́run,Fi àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ dá mi lóhùn.+