Òwe 12:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ètè tó ń sọ òtítọ́ máa wà títí láé,+Àmọ́ ahọ́n tó ń parọ́ kò ní tọ́jọ́.+ Òwe 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ahọ́n pẹ̀lẹ́* jẹ́ igi ìyè,+Àmọ́ ọ̀rọ̀ békebèke máa ń fa ìrẹ̀wẹ̀sì.* 1 Pétérù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí náà, ẹ jáwọ́ nínú gbogbo ìwà burúkú,+ ẹ̀tàn, àgàbàgebè àti owú, ẹ má sì sọ̀rọ̀ ẹnikẹ́ni láìdáa.
2 Nítorí náà, ẹ jáwọ́ nínú gbogbo ìwà burúkú,+ ẹ̀tàn, àgàbàgebè àti owú, ẹ má sì sọ̀rọ̀ ẹnikẹ́ni láìdáa.