ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 19:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Torí náà, Jónátánì sọ̀rọ̀ Dáfídì ní rere+ níwájú Sọ́ọ̀lù bàbá rẹ̀. Ó sọ fún un pé: “Kí ọba má ṣàìdáa sí* Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ̀, nítorí kò ṣẹ̀ ọ́, àwọn ohun tó ṣe fún ọ sì ti ṣe ọ́ láǹfààní. 5 Ó fi ẹ̀mí rẹ̀ wewu* kó lè pa Filísínì náà,+ tí Jèhófà sì mú kí gbogbo Ísírẹ́lì ṣẹ́gun* lọ́nà tó kàmàmà. O rí i, inú rẹ sì dùn gan-an. Kí ló wá dé tí o fẹ́ fi pa Dáfídì láìnídìí, tí wàá sì ní ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ lọ́rùn?”+

  • 1 Sámúẹ́lì 20:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ni Sọ́ọ̀lù bá ju ọ̀kọ̀ sí i láti fi gún un,+ Jónátánì sì wá mọ̀ pé bàbá òun ti pinnu láti pa Dáfídì.+

  • Jeremáyà 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ṣé ó yẹ kéèyàn fi ibi san ire?

      Nítorí wọ́n ti gbẹ́ kòtò fún ẹ̀mí* mi.+

      Rántí bí mo ṣe dúró níwájú rẹ láti sọ ohun tó dáa nípa wọn,

      Kí o lè yí ìbínú rẹ kúrò lórí wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́