ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 31:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Mo ti gbọ́ ọ̀pọ̀ àhesọ burúkú;

      Àwọn ohun ẹ̀rù yí mi ká.+

      Nígbà tí wọ́n kóra jọ lé mi lórí,

      Wọ́n gbèrò láti gba ẹ̀mí* mi.+

  • Jeremáyà 11:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Mo dà bí ọ̀dọ́ àgùntàn tí kò lágbaja tí wọ́n ń mú bọ̀ níbi tí wọ́n ti fẹ́ pa á.

      Mi ò mọ̀ pé wọ́n ń gbèrò ohun búburú sí mi pé:+

      “Ẹ jẹ́ ká pa igi náà àti èso rẹ̀ run,

      Ká sì gé e kúrò ní ilẹ̀ alààyè,

      Kí a má bàa rántí orúkọ rẹ̀ mọ́.”

  • Mátíù 26:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 wọ́n sì gbìmọ̀ pọ̀+ kí wọ́n lè fi ọgbọ́n àrékérekè* mú* Jésù, kí wọ́n sì pa á.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́