Sáàmù 25:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ta ni ẹni tó ń bẹ̀rù Jèhófà?+ Òun yóò kọ́ ẹni náà ní ọ̀nà tó yẹ kí ó yàn.+ נ [Núnì] 13 Yóò* gbádùn ohun rere,+Àwọn àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ yóò sì jogún ayé.+ Sáàmù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn olódodo ni yóò jogún ayé,+Wọn yóò sì máa gbé inú rẹ̀ títí láé.+ Mátíù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Aláyọ̀ ni àwọn oníwà tútù,*+ torí wọ́n máa jogún ayé.+ 2 Pétérù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+
12 Ta ni ẹni tó ń bẹ̀rù Jèhófà?+ Òun yóò kọ́ ẹni náà ní ọ̀nà tó yẹ kí ó yàn.+ נ [Núnì] 13 Yóò* gbádùn ohun rere,+Àwọn àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ yóò sì jogún ayé.+
9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+