Sáàmù 34:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jáwọ́ nínú ohun búburú, kí o sì máa ṣe rere;+Máa wá àlàáfíà, kí o sì máa lépa rẹ̀.+ Àìsáyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ kọ́ bí ẹ ṣe máa ṣe rere, ẹ wá ìdájọ́ òdodo,+Ẹ tọ́ àwọn aninilára sọ́nà;Ẹ gbèjà àwọn ọmọ aláìníbaba,*Kí ẹ sì gba ẹjọ́ opó rò.”+
17 Ẹ kọ́ bí ẹ ṣe máa ṣe rere, ẹ wá ìdájọ́ òdodo,+Ẹ tọ́ àwọn aninilára sọ́nà;Ẹ gbèjà àwọn ọmọ aláìníbaba,*Kí ẹ sì gba ẹjọ́ opó rò.”+