ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 37:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Yẹra fún ohun búburú, máa ṣe rere,+

      Wàá sì máa gbé ayé títí láé.

  • Sáàmù 97:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+

      Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+

      Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+

  • Émọ́sì 5:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ẹ kórìíra ohun búburú, kí ẹ sì nífẹ̀ẹ́ ohun rere,+

      Ẹ jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo gbilẹ̀ ní ẹnubodè ìlú.+

      Bóyá Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun

      Máa fi ojúure hàn sí àwọn tó ṣẹ́ kù lára Jósẹ́fù.’+

  • Róòmù 12:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ẹ jẹ́ kí ìfẹ́ yín wà láìsí ẹ̀tàn.*+ Ẹ kórìíra ohun búburú;+ ẹ rọ̀ mọ́ ohun rere.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́