Sáàmù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọ̀pọ̀ ń sọ nípa mi* pé: “Ọlọ́run ò ní gbà á sílẹ̀.”+ (Sélà)* Sáàmù 71:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí mi,Àwọn tó sì fẹ́ gba ẹ̀mí* mi gbìmọ̀ pọ̀,+11 Wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run ti pa á tì. Ẹ lé e, kí ẹ sì mú un, torí kò sẹ́ni tó máa gbà á sílẹ̀.”+
2 Ọ̀pọ̀ ń sọ nípa mi* pé: “Ọlọ́run ò ní gbà á sílẹ̀.”+ (Sélà)* Sáàmù 71:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí mi,Àwọn tó sì fẹ́ gba ẹ̀mí* mi gbìmọ̀ pọ̀,+11 Wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run ti pa á tì. Ẹ lé e, kí ẹ sì mú un, torí kò sẹ́ni tó máa gbà á sílẹ̀.”+
10 Àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí mi,Àwọn tó sì fẹ́ gba ẹ̀mí* mi gbìmọ̀ pọ̀,+11 Wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run ti pa á tì. Ẹ lé e, kí ẹ sì mú un, torí kò sẹ́ni tó máa gbà á sílẹ̀.”+