ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 26:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ máa ń wà níwájú mi nígbà gbogbo,

      Mo sì ń rìn nínú òtítọ́ rẹ.+

  • Sáàmù 40:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Mi ò bo òdodo rẹ mọ́lẹ̀ nínú ọkàn mi.

      Mo kéde ìṣòtítọ́ rẹ àti ìgbàlà rẹ.

      Mi ò fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ pa mọ́ nínú ìjọ ńlá.”+

  • Sáàmù 63:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ sàn ju ìyè,+

      Ètè mi yóò máa yìn ọ́ lógo.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́