Àìsáyà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa kọ orin yìí+ ní ilẹ̀ Júdà:+ “A ní ìlú tó lágbára.+ Ó fi ìgbàlà ṣe àwọn ògiri rẹ̀, ó sì fi mọ òkìtì yí i ká.+
26 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa kọ orin yìí+ ní ilẹ̀ Júdà:+ “A ní ìlú tó lágbára.+ Ó fi ìgbàlà ṣe àwọn ògiri rẹ̀, ó sì fi mọ òkìtì yí i ká.+