-
Jeremáyà 7:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Torí láti ọjọ́ tí mo ti mú àwọn baba ńlá yín jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, mi ò bá wọn sọ̀rọ̀ tàbí kí n pàṣẹ fún wọn lórí àwọn odindi ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ.+ 23 Ṣùgbọ́n, mo pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ gbọ́ràn sí mi lẹ́nu, màá sì di Ọlọ́run yín, ẹ ó sì di èèyàn mi.+ Kí ẹ máa rìn ní ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fún yín, kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún yín.”’+
-