-
Míkà 6:6-8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kí ni màá mú wá síwájú Jèhófà?
Kí sì ni màá mú wá tí mo bá wá tẹrí ba fún Ọlọ́run lókè?
Ṣé odindi ẹbọ sísun ni màá gbé wá síwájú rẹ̀,
Àwọn ọmọ màlúù ọlọ́dún kan?+
7 Ṣé inú Jèhófà máa dùn sí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àgbò,
Sí ẹgbẹẹgbàárùn-ún ìṣàn òróró?+
8 Ó ti sọ ohun tó dára fún ọ, ìwọ ọmọ aráyé.
Kí sì ni Jèhófà fẹ́ kí o ṣe?*
-