ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 2:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Làákàyè yóò máa ṣọ́ ọ,+

      Ìfòyemọ̀ yóò sì máa dáàbò bò ọ́,

  • Òwe 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Yóò dáàbò bò ọ́ kúrò lọ́wọ́ obìnrin oníwàkiwà,*

      Kúrò lọ́wọ́ ọ̀rọ̀ dídùn* obìnrin oníṣekúṣe,*+

  • Òwe 5:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí ètè obìnrin oníwàkiwà* ń kán tótó bí afárá oyin,+

      Ọ̀rọ̀* rẹ̀ sì tuni lára ju òróró lọ.+

  • Òwe 6:23, 24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Nítorí àṣẹ jẹ́ fìtílà,+

      Òfin jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+

      Àwọn ẹ̀kọ́ inú ìbáwí sì ni ọ̀nà ìyè.+

      24 Wọ́n máa dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ obìnrin burúkú,+

      Lọ́wọ́ ahọ́n obìnrin oníṣekúṣe* tó ń sọ ọ̀rọ̀ tó fani mọ́ra.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́