Oníwàásù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ kò ní dára fún ẹni burúkú,+ bẹ́ẹ̀ ni kò lè mú kí àwọn ọjọ́ rẹ̀ tó dà bí òjìji gùn,+ nítorí kò bẹ̀rù Ọlọ́run. Ìsíkíẹ́lì 18:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Gbogbo ọkàn,* tèmi ni wọ́n. Bí ọkàn bàbá ti jẹ́ tèmi, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ọmọ. Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.
13 Àmọ́ kò ní dára fún ẹni burúkú,+ bẹ́ẹ̀ ni kò lè mú kí àwọn ọjọ́ rẹ̀ tó dà bí òjìji gùn,+ nítorí kò bẹ̀rù Ọlọ́run.
4 Wò ó! Gbogbo ọkàn,* tèmi ni wọ́n. Bí ọkàn bàbá ti jẹ́ tèmi, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ọmọ. Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.