Òwe 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹni tó ń ṣọ́ ẹnu rẹ̀* ń dáàbò bo ẹ̀mí* rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó ń la ẹnu rẹ̀ gbàgà yóò pa run.+