2 Tí ọkùnrin kan bá jẹ́jẹ̀ẹ́+ fún Jèhófà tàbí tó búra+ pé òun máa* yẹra fún nǹkan kan, kò gbọ́dọ̀ yẹ ọ̀rọ̀ rẹ̀.+ Gbogbo ohun tó jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun máa ṣe ni kó ṣe.+
6 Má ṣe jẹ́ kí ẹnu rẹ mú ọ* dẹ́ṣẹ̀,+ má sì sọ níwájú áńgẹ́lì* pé àṣìṣe ni.+ Kí nìdí tí wàá fi mú Ọlọ́run tòótọ́ bínú nítorí ohun tí o sọ, tí á sì pa iṣẹ́ ọwọ́ rẹ run?+