-
Sáàmù 127:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Bí Jèhófà ò bá ṣọ́ ìlú,+
Lásán ni ẹ̀ṣọ́ wà lójúfò.
-
-
Hágáì 1:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Mo sì mú kí ọ̀dá wà lórí ayé, lórí àwọn òkè, lórí ọkà, lórí wáìnì tuntun, lórí òróró, lórí ohun tó ń hù lórí ilẹ̀, lórí èèyàn àti ẹran ọ̀sìn àti gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ yín.’”
-