Sáàmù 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Sáàmù 33:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ẹṣin pé á gbani là* jẹ́ asán;+Agbára ńlá rẹ̀ kò sọ pé kéèyàn yè bọ́. Àìsáyà 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.
7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+
31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.