Sáàmù 141:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn. Òwe 27:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọgbẹ́ tí ọ̀rẹ́ dá síni lára jẹ́ ìṣòtítọ́,+Àmọ́ ìfẹnukonu ọ̀tá pọ̀ rẹpẹtẹ.*
5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn.