Sáàmù 55:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ ìwọ, Ọlọ́run, yóò rẹ̀ wọ́n wálẹ̀ sínú kòtò tó jìn jù lọ.+ Àwọn tó jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀, tí wọ́n sì jẹ́ ẹlẹ́tàn kò ní lo ààbọ̀ ọjọ́ ayé wọn.+ Àmọ́ ní tèmi, màá gbẹ́kẹ̀ lé ọ. Òwe 10:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìbẹ̀rù Jèhófà ń mú kí ẹ̀mí ẹni gùn,+Àmọ́ ọdún àwọn ẹni burúkú ni a ó gé kúrú.+
23 Àmọ́ ìwọ, Ọlọ́run, yóò rẹ̀ wọ́n wálẹ̀ sínú kòtò tó jìn jù lọ.+ Àwọn tó jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀, tí wọ́n sì jẹ́ ẹlẹ́tàn kò ní lo ààbọ̀ ọjọ́ ayé wọn.+ Àmọ́ ní tèmi, màá gbẹ́kẹ̀ lé ọ.