Jémíìsì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí gbogbo wa ni a máa ń kọsẹ̀* lọ́pọ̀ ìgbà.+ Tí ẹnì kan kì í bá ṣi ọ̀rọ̀ sọ, á jẹ́ pé ẹni pípé ni, ó sì lè kó gbogbo ara rẹ̀ níjàánu. Jémíìsì 3:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ kò sí èèyàn tó lè kápá ahọ́n. Aláìgbọràn ni, ó sì ń ṣeni léṣe, ó kún fún májèlé tó ń pani.+ 9 Òun la fi ń yin Jèhófà,* Baba wa, síbẹ̀ òun la tún fi ń gégùn-ún fún àwọn èèyàn tí a dá ní “àwòrán Ọlọ́run.”+
2 Nítorí gbogbo wa ni a máa ń kọsẹ̀* lọ́pọ̀ ìgbà.+ Tí ẹnì kan kì í bá ṣi ọ̀rọ̀ sọ, á jẹ́ pé ẹni pípé ni, ó sì lè kó gbogbo ara rẹ̀ níjàánu.
8 Àmọ́ kò sí èèyàn tó lè kápá ahọ́n. Aláìgbọràn ni, ó sì ń ṣeni léṣe, ó kún fún májèlé tó ń pani.+ 9 Òun la fi ń yin Jèhófà,* Baba wa, síbẹ̀ òun la tún fi ń gégùn-ún fún àwọn èèyàn tí a dá ní “àwòrán Ọlọ́run.”+