20 Nígbà tí Ákánì+ ọmọ Síírà hùwà àìṣòótọ́ lórí ọ̀rọ̀ ohun tí a máa pa run, ṣebí gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ni Ọlọ́run bínú sí?+ Òun nìkan kọ́ ló kú torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.’”+
15 Ẹ kíyè sára gidigidi ká má bàa rí ẹnikẹ́ni tí kò ní gba inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, kí gbòǹgbò kankan tó ní májèlé má bàa rú yọ láti dá wàhálà sílẹ̀, kó sì sọ ọ̀pọ̀ di aláìmọ́;+