ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 71:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ọlọ́run, o ti kọ́ mi láti ìgbà èwe mi wá,+

      Títí di báyìí, mò ń kéde àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.+

  • Sáàmù 148:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ẹ yin Jèhófà láti ayé,

      Ẹ̀yin ẹ̀dá ńlá inú òkun àti gbogbo ẹ̀yin ibú omi,

  • Sáàmù 148:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin àti ẹ̀yin ọ̀dọ́bìnrin,*

      Ẹ̀yin àgbà ọkùnrin àti ẹ̀yin ọ̀dọ́.*

  • Lúùkù 2:48, 49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ rí i, ẹnu yà wọ́n, ìyá rẹ̀ wá sọ fún un pé: “Ọmọ, kí ló dé tí o fi ṣe báyìí sí wa? Wò ó, èmi àti bàbá rẹ ti dààmú gan-an bá a ṣe ń wá ọ kiri.” 49 Àmọ́ ó sọ fún wọn pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń wá mi? Ṣé ẹ ò mọ̀ pé mo gbọ́dọ̀ wà nínú ilé Baba mi ni?”+

  • 2 Tímótì 3:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 àti pé láti kékeré jòjòló  + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́