Sáàmù 39:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Dájúdájú, bí òjìji ni ọmọ èèyàn ń rìn kiri. Ó ń sáré kiri* lórí òfo. Ó ń kó ọrọ̀ jọ pelemọ láìmọ ẹni tó máa gbádùn rẹ̀.+ Lúùkù 12:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ Ọlọ́run sọ fún un pé, ‘Aláìlóye, òru òní ni wọ́n máa béèrè ẹ̀mí* rẹ lọ́wọ́ rẹ. Ta ló máa wá ni àwọn ohun tí o ti tò jọ?’+
6 Dájúdájú, bí òjìji ni ọmọ èèyàn ń rìn kiri. Ó ń sáré kiri* lórí òfo. Ó ń kó ọrọ̀ jọ pelemọ láìmọ ẹni tó máa gbádùn rẹ̀.+
20 Àmọ́ Ọlọ́run sọ fún un pé, ‘Aláìlóye, òru òní ni wọ́n máa béèrè ẹ̀mí* rẹ lọ́wọ́ rẹ. Ta ló máa wá ni àwọn ohun tí o ti tò jọ?’+