Sáàmù 15:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà, ta ló lè jẹ́ àlejò nínú àgọ́ rẹ? Ta ló lè máa gbé ní òkè mímọ́ rẹ?+ 2 Ẹni tó ń rìn láìlẹ́bi,*+Tó ń ṣe ohun tí ó tọ́+Tó sì ń sọ òtítọ́ nínú ọkàn rẹ̀.+
15 Jèhófà, ta ló lè jẹ́ àlejò nínú àgọ́ rẹ? Ta ló lè máa gbé ní òkè mímọ́ rẹ?+ 2 Ẹni tó ń rìn láìlẹ́bi,*+Tó ń ṣe ohun tí ó tọ́+Tó sì ń sọ òtítọ́ nínú ọkàn rẹ̀.+