ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Orin Sólómọ́nì 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “Wò ó! O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi.

      Wò ó! O rẹwà gan-an. Ojú rẹ rí bíi ti àdàbà.”+

  • Orin Sólómọ́nì 4:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 O ti gbà mí lọ́kàn,+ arábìnrin mi, ìyàwó mi,

      Bí o ṣe ṣíjú wò mí báyìí, tí mo rí ọ̀kan nínú ẹ̀gbà ọrùn rẹ,

      Bẹ́ẹ̀ lo gbà mí lọ́kàn.

  • Orin Sólómọ́nì 7:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ọrùn rẹ+ dà bí ilé gogoro+ tí wọ́n fi eyín erin kọ́.

      Ojú rẹ+ dà bí àwọn omi Hẹ́ṣíbónì,+

      Lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè Bati-rábímù.

      Imú rẹ dà bí ilé gogoro Lẹ́bánónì,

      Tó dojú kọ Damásíkù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́