Sáàmù 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn ọ̀run ń polongo ògo Ọlọ́run;+Ojú ọ̀run* sì ń kéde iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.+ Róòmù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí àwọn ànímọ́* rẹ̀ tí kò ṣeé fojú rí ni a rí ní kedere láti ìgbà ìṣẹ̀dá ayé síwájú, torí à ń fi òye mọ̀ wọ́n látinú àwọn ohun tó dá,+ títí kan agbára ayérayé tó ní+ àti bó ṣe jẹ́ Ọlọ́run,+ tó fi jẹ́ pé wọn ò ní àwíjàre.
20 Nítorí àwọn ànímọ́* rẹ̀ tí kò ṣeé fojú rí ni a rí ní kedere láti ìgbà ìṣẹ̀dá ayé síwájú, torí à ń fi òye mọ̀ wọ́n látinú àwọn ohun tó dá,+ títí kan agbára ayérayé tó ní+ àti bó ṣe jẹ́ Ọlọ́run,+ tó fi jẹ́ pé wọn ò ní àwíjàre.