Àìsáyà 51:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí Jèhófà máa tu Síónì nínú.+ Ó máa tu gbogbo àwókù rẹ̀ nínú,+Ó máa mú kí aginjù rẹ̀ rí bí Édẹ́nì,+Ó sì máa mú kí aṣálẹ̀ rẹ̀ tó tẹ́jú rí bí ọgbà Jèhófà.+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa wà níbẹ̀,Ìdúpẹ́ àti orin tó dùn.+ Àìsáyà 55:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dípò àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, igi júnípà máa hù,+Dípò èsìsì tó ń jóni lára, igi mátílì máa hù. Ó sì máa mú kí Jèhófà lókìkí,*+Àmì tó máa wà títí láé, tí kò ní pa run.”
3 Torí Jèhófà máa tu Síónì nínú.+ Ó máa tu gbogbo àwókù rẹ̀ nínú,+Ó máa mú kí aginjù rẹ̀ rí bí Édẹ́nì,+Ó sì máa mú kí aṣálẹ̀ rẹ̀ tó tẹ́jú rí bí ọgbà Jèhófà.+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa wà níbẹ̀,Ìdúpẹ́ àti orin tó dùn.+
13 Dípò àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, igi júnípà máa hù,+Dípò èsìsì tó ń jóni lára, igi mátílì máa hù. Ó sì máa mú kí Jèhófà lókìkí,*+Àmì tó máa wà títí láé, tí kò ní pa run.”