26 Ẹni tó ń mú kí ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣẹ,
Tó sì ń mú àsọtẹ́lẹ̀ àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀ ṣẹ délẹ̀délẹ̀;+
Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa gbé inú rẹ̀’+
Àti nípa àwọn ìlú Júdà pé, ‘Wọ́n máa tún wọn kọ́,+
Màá sì mú kí àwọn ibi tó ti dahoro níbẹ̀ pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀’;+
-
Àìsáyà 61:4
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Wọ́n máa tún àwọn ibi tó ti pa run nígbà àtijọ́ kọ́;
Wọ́n máa kọ́ àwọn ibi tó ti dahoro nígbà àtijọ́,+
Wọ́n sì máa mú kí àwọn ìlú tó ti pa run pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀,+
Àwọn ibi tó ti wà ní ahoro láti ìran dé ìran.+