Àìsáyà 44:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ta ló máa ṣe ọlọ́run tàbí kó ṣe ère onírin* Tí kò lè ṣàǹfààní rárá?+ 11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+ Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà. Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró. Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀. Àìsáyà 45:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ojú máa ti gbogbo wọn, wọ́n sì máa tẹ́;Ìtìjú ni gbogbo àwọn tó ń ṣe ère máa bá kúrò.+
10 Ta ló máa ṣe ọlọ́run tàbí kó ṣe ère onírin* Tí kò lè ṣàǹfààní rárá?+ 11 Wò ó! Ojú máa ti gbogbo àwọn alájọṣe rẹ̀!+ Èèyàn lásán ni àwọn oníṣẹ́ ọnà. Kí gbogbo wọn kóra jọ, kí wọ́n sì dúró. Jìnnìjìnnì máa bò wọ́n, ojú sì máa tì wọ́n pa pọ̀.