Ìsíkíẹ́lì 34:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Èmi yóò mú kí wọ́n di ìbùkún, màá mú kí ibi tó yí òkè mi ká náà di ìbùkún,+ màá sì mú kí òjò rọ̀ ní àkókò tó yẹ. Ìbùkún á rọ̀ bí òjò.+
26 Èmi yóò mú kí wọ́n di ìbùkún, màá mú kí ibi tó yí òkè mi ká náà di ìbùkún,+ màá sì mú kí òjò rọ̀ ní àkókò tó yẹ. Ìbùkún á rọ̀ bí òjò.+