Jẹ́nẹ́sísì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, Ọlọ́run dá ọ̀run àti ayé.+ Àìsáyà 40:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+
28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+