Jeremáyà 30:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, gbogbo àwọn tó ń pa àwọn èèyàn rẹ run ni a ó pa run,+Gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ á sì lọ sí oko ẹrú.+ Àwọn tó ń fi ogun kó ọ ni a ó fi ogun kó,Àwọn tó ń kó ọ lẹ́rù ni màá sì jẹ́ kí wọ́n kó lẹ́rù lọ.”+
16 Nítorí náà, gbogbo àwọn tó ń pa àwọn èèyàn rẹ run ni a ó pa run,+Gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ á sì lọ sí oko ẹrú.+ Àwọn tó ń fi ogun kó ọ ni a ó fi ogun kó,Àwọn tó ń kó ọ lẹ́rù ni màá sì jẹ́ kí wọ́n kó lẹ́rù lọ.”+