ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 48:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+

      Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà!

      Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+

      Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+

      Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+

  • Jeremáyà 50:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 “Ẹ sá kúrò nínú Bábílónì,

      Ẹ jáde kúrò ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà,+

      Kí ẹ sì dà bí àgbò tó ń ṣíwájú agbo ẹran.

  • Jeremáyà 51:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ẹ sá kúrò nínú Bábílónì,

      Kí ẹ sì sá nítorí ẹ̀mí* yín.+

      Ẹ má ṣègbé nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

      Nítorí àkókò ẹ̀san Jèhófà ti tó.

      Ó máa san ohun tó ṣe pa dà fún un.+

  • Sekaráyà 2:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Jèhófà kéde pé, “Ẹ wá! Ẹ wá! Ẹ sá kúrò ní ilẹ̀ àríwá.”+

      “Torí mo ti fọ́n yín káàkiri,”*+ ni Jèhófà wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́