ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 13:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ìwọ idà, dìde sí olùṣọ́ àgùntàn mi,+

      Sí ọkùnrin tó jẹ́ ọ̀rẹ́ mi.

      Kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ kí agbo* sì tú ká;+

      Èmi yóò sì yí ọwọ́ mi pa dà sí àwọn tí kò já mọ́ nǹkan kan.”

  • Jòhánù 11:49, 50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 Àmọ́ ọ̀kan lára wọn, Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ nǹkan kan rárá, 50 ẹ ò sì rò ó pé ó máa ṣe yín láǹfààní pé kí ọkùnrin kan kú torí àwọn èèyàn dípò kí gbogbo orílẹ̀-èdè pa run.”

  • Róòmù 5:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Torí, ní tòótọ́, nígbà tí a ṣì jẹ́ aláìlera,+ Kristi kú fún àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ní àkókò tí a yàn.

  • Hébérù 9:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ì bá máa jìyà léraléra látìgbà ìpìlẹ̀ ayé. Àmọ́ ní báyìí, ó ti fi ara rẹ̀ hàn kedere ní ìparí àwọn ètò àwọn nǹkan,* lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé, ó fi ara rẹ̀ rúbọ kó lè mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́