ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 9:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 “A ti pinnu àádọ́rin (70) ọ̀sẹ̀* fún àwọn èèyàn rẹ àti ìlú mímọ́ rẹ,+ láti fòpin sí àṣìṣe, láti pa ẹ̀ṣẹ̀ rẹ́,+ láti ṣe ètùtù torí ìṣìnà,+ láti mú òdodo tó máa wà títí láé wá,+ láti gbé èdìdì lé ìran náà àti àsọtẹ́lẹ̀*+ àti láti fòróró yan Ibi Mímọ́ nínú Àwọn Ibi Mímọ́.*

  • Hébérù 7:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Kò nílò kó máa rúbọ lójoojúmọ́,+ bíi ti àwọn àlùfáà àgbà yẹn, fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tiẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, lẹ́yìn náà fún ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn,+ torí ó ti ṣe èyí nígbà tó fi ara rẹ̀ rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé.+

  • 1 Pétérù 3:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀, Kristi kú lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún kú mọ́ láé,+ ó jẹ́ olódodo tó kú nítorí àwọn aláìṣòdodo,+ kó lè mú yín wá sọ́dọ̀ Ọlọ́run.+ Wọ́n pa á nínú ẹran ara,+ àmọ́ a sọ ọ́ di ààyè nínú ẹ̀mí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́